Abánikọ̀rọ̀ Yorùbá

Tẹ̀ tàbí kóo ṣẹ̀dà oun tí o fẹ́ kí á bá ẹ kọ sínú ààyè funfun yẹ, kí o sì tẹ bọ́tìnì Bánikọ̀rọ̀. A ó kọ Músá sí inú ààyè aláwọ̀ òfefe ti Músá. Àwọn ọ̀rọ̀ Yorùbá yìí lè jẹ́ ti Nàìjíríyà tàbí ti Togo tàbí ti Benin, àkọsílẹ̀ ńlá tàbí kékeré. Gbogbo oun ààmì tí a bá kọ síbẹ̀ ni a ó lo ààmì Músá tí kò pójú ìwọ̀n láti kọ. Nítorínáà, kí o yẹ̀ẹ́wò lẹ́ẹ̀kansíi láti ṣe àtúnṣẹ sí gbogbo ààmì ibẹ̀. Abánikọ̀rọ̀ yìí lè kojú àwọn nọ́mbà, ṣùgbọ́n kò ní ṣiṣẹ́ dáadáa lórí àwọn ọ̀rọ̀ àjèjì, nítorínáà, wàá nílò láti tún àwọn èyí náà kọ.

Type or paste the text to be transcribed into the white box, and press the Bánikọ̀rọ̀ button. The Musa will be added to the yellow Musa box. The Yorùbá text can be Nigerian/Togolese or Beninese, uppercase or lowercase, and any punctuation will be transcribed using the Musa defective punctuation - you should go over it afterwards to correct the punctuation. The transcriber can handle numbers, but it won't do well on foreign words, so you'll have to edit those, too. The Yẹ̀wò button runs some checks on the text, the Ṣẹ̀dà sí Àtẹ button copies it to the clipboard, and the Parẹ́ clears the page.

Bánikọ̀rọ̀ Yẹ̀wò Ṣẹ̀dà sí Àtẹ Parẹ́